Ooh nah
Yeah
I'm a Naijá Boy
Naijá
Lórí mi
Eh hen Eh hen
Lórí mi
Aye
Lórí mi
Eh hen Eh hen
Lórí mi
Ìbùkún olórun lórí mi
Ẹ̀jẹ̀ olórun lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Ọ̀wọ̀ lani lórí mi
Ìlera to dára lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Olórun mi lágbára olódùmarè ni olórun mi
Kó kùnà nì Bàbá mi oshé Bàbá fún ayé mi
Blessings for me it's plenty
Lagos Ibadan to Lekki
Port Harcourt Abuja to Benin o
My God he never go fail me o
Ìbùkún olórun lórí mi
Ẹ̀jẹ̀ olórun lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí lórí mi
Ahh
Lórí mi
Ọ̀wọ̀ lani lórí mi
Ìlera to dára lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Chop àmàlà
Chop akara
No wàhálà
Oshé Bàbá
Olùpamó
Olùgbàlà
Olù Jesu
Oshé Bàbá o
Celebrate with shayo
God take me higher
Take me higher
Yeah
Ìbùkún olórun lórí mi
Ẹ̀jẹ̀ olórun lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Ọ̀wọ̀ lani lórí mi
Ìlera to dára lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Ìbùkún olórun lórí mi
Ẹ̀jẹ̀ olórun lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi
Ọ̀wọ̀ lani lórí mi
Ìlera to dára lórí mi
Ifẹ̀ olórun lórí mi
Ahh
Lórí mi