Ọmọ Ológo tí gbéra sọ
Ọlọ́run ti gbe mí sókè
I'm flying like eagle
Eh eh eh eh eh eh
Ògo mí ti wọn ro pé kole tan
Ìyẹn dè ti dí global loju aráyé
Oba Ògo sa là là ti lẹhin mi
Tó ń fí mi sá fihàn loju aráyé
Maje kó gbéra ni wón wi
Kó má má ni bú yọ ní won lero
Oba Ògo sa tí fun mi ni backing
Ògo mi di eagle loju aráyé
Oya so ti e ṣe
Ògo mí ti wọn ro pé kole tan (Omo ológo ti gbéra sọ baba o)
Ìyẹn dè ti dí global loju aráyé
Oba Ògo sa là là ti lẹhin mi
Tó ń fí mi sá fihàn loju aráyé
Oya gbéra dìde se
Maje kó gbéra ni wón wi
(Olorun tí gbé mi sókè )
Kó má má ni bú yọ ní won lero (Personally baba)
Oba Ògo sa tí fun mi ni backing(Omo ológo ti gbéra sọ )
Ògo mi di eagle loju aráyé
O na na na na na na na
O o o o o o o o o o
Olorun ti ṣe oti gbe mí sókè mo ti bori o
Mo n gara mo n yàn fanda mo ti gbéra
Maje kó gbéra ni wón wi (Baba ti ba mi ṣe )
Kó má má ni bú yọ ní won lero
(Oti gbé mi sókè ga ga )
Oba Ògo sa tí fun mi ni backing
(I'm flying like eagle)
Ògo mi di eagle loju aráyé ( Ose Olorun)